Reminisce – Orin Lyrics

Reminisce Orin Lyrics (feat. Olamide)

How many woes?
How many foes?
How many struggle and fight?
How many sweat and tears, and blood I have to shed to be a man? Oh
E no easy I know
Dem want take me down low
Cause the wire never slowing down woah!

Gbọpẹ lọ, ọmọ oro gbọpẹ lọ (Gbọpẹ)
Ẹ ṣe gan-an
Ṣẹ ti gbọ orin t’ọn n kọ? (Ẹ ṣe gan-an)
Gbọpẹ lọ, ọmọ oro gbọpẹ lọ (Gbọpẹ)
Ẹ ṣe gan-an
Ṣẹ ti gbọ orin t’ọn n kọ?

Ṣẹ ti gbọ orin t’ọn n kọ?
Isọkusọ t’ọn sọ
Gbogbo ikọkukọ t’ọn n kọ
Just bacause awa lọmọ t’ọn n sọ

Long time coming , but boys still running
Tap wọn ti gbẹ but ours still running
Ọta wọn ti wọn Topboys still gunning
Sperm wọn ti gbẹ ọmọ oro still cumming

Oju lasan lẹ ro pe wọn fi n di legende
Ẹ tẹ’pa mọ’ṣẹ ẹ fẹ di elpresidente
Ibo lẹ wa nigba ti mo n hustle ni Ebivande?
Dasaki, ko n tan lara ọmọ ọba men dey

Rule number 1, do more say less
Normally too much opata dey bring stress
Even when I don’t agree I’m gonna say yes
Baddo fayẹwo gbe hook yẹn wọle bi safe sex

How many woes?
How many foes?
How many struggle and fight?
How many sweat and tears, and blood I have to shed to be a man? Oh
E no easy I know
Dem want take me down low
Cause the wire never slowing down woah!

Gbọpẹ lọ, ọmọ oro gbọpẹ lọ (Gbọpẹ)
Ẹ ṣe gan-an
Ṣẹ ti gbọ orin t’ọn n kọ? (Ẹ ṣe gan-an)
Gbọpẹ lọ, ọmọ oro gbọpẹ lọ (Gbọpẹ)
Ẹ ṣe gan-an
Ṣẹ ti gbọ orin t’ọn n kọ?

10 years in the trenches
12 years on top lai ṣe menses
Can’t do nothing right, wọn ṣi ma fo
Bi ọṣẹ detergent, wọn ṣi ma ho

Reputation stainless
Been through tough times so I know what pain is
Seen a lotta sunshine so I know why rain is
Seen a lotta good days so I know what day it is

Nothing’s gonna stop me o digba ti n ba jabọ
In about 6/7 decades mo ni igbagbọ
Ma kanra kanra everyday like it’s my last
Marathon lere fuji yii mi o dẹ le gas

Examination ni mo dẹ ti pass
Ọja D baba eeyan best in class
GOAT conversations? Kiss my ass
Fuck all you rap n*****, kalaz

How many woes?
How many foes?
How many struggle and fight?
How many sweat and tears, and blood I have to shed to be a man? Oh
E no easy I know
Dem want take me down low
Cause the wire never slowing down woah!

Gbọpẹ lọ, ọmọ oro gbọpẹ lọ (Gbọpẹ)
Ẹ ṣe gan-an
Ṣẹ ti gbọ orin t’ọn n kọ? (Ṣẹ ti gbọ orin t’ọn n kọ?)
Gbọpẹ lọ, ọmọ oro gbọpẹ lọ (Gbọpẹ)
Ẹ ṣe gan-an
Ṣẹ ti gbọ orin t’ọn n kọ?

    Lyrics Knowledge:

  • Written by: Reminisce, Olamide
  • Album: ATSG, Vol. 1
  • Released: 2023